Hymn 762 – Eyin ara nu Krist

Hymn 762 – Eyin ara nu Krist
By GTG – BOLT

Eyin ara nu Krist
E gbe orin soke
K’e si gbo ohun
Ti Jehovah n so
Ere’di re t’e fi wa
Ninu ijo Mimo yi?
Ere’di re t’e fi wa
Ninu egbe nla yi?
Ki Maria iya wa
Le e wa a sin wa lo
K’eni Mimo rere yi
Wa ma sin wa lo
Amin

Trending Testimonies

The true use of your God is seen in your testimony!